Jóòbù 33:28-30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ó ti ra ọkàn* mi pa dà kó má bàa lọ sínú kòtò,*+Ẹ̀mí mi sì máa rí ìmọ́lẹ̀.’ 29 Lóòótọ́, Ọlọ́run máa ń ṣe gbogbo nǹkan yìíFún èèyàn, lẹ́ẹ̀mejì, lẹ́ẹ̀mẹta,30 Láti mú un* pa dà kúrò nínú kòtò,*Kí ìmọ́lẹ̀ ìyè+ lè là á lóye.
28 Ó ti ra ọkàn* mi pa dà kó má bàa lọ sínú kòtò,*+Ẹ̀mí mi sì máa rí ìmọ́lẹ̀.’ 29 Lóòótọ́, Ọlọ́run máa ń ṣe gbogbo nǹkan yìíFún èèyàn, lẹ́ẹ̀mejì, lẹ́ẹ̀mẹta,30 Láti mú un* pa dà kúrò nínú kòtò,*Kí ìmọ́lẹ̀ ìyè+ lè là á lóye.