Àìsáyà 13:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ìdí nìyẹn tí màá fi mú kí ọ̀run gbọ̀n rìrì,Ayé sì máa mì jìgìjìgì kúrò ní àyè rẹ̀+Nígbà tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun bá bínú gidigidi ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná. Hébérù 12:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nígbà yẹn, ohùn rẹ̀ mi ayé jìgìjìgì,+ àmọ́ ní báyìí, ó ti ṣèlérí pé: “Lẹ́ẹ̀kan sí i, kì í ṣe ayé nìkan ni màá mì jìgìjìgì, màá mi ọ̀run pẹ̀lú.”+
13 Ìdí nìyẹn tí màá fi mú kí ọ̀run gbọ̀n rìrì,Ayé sì máa mì jìgìjìgì kúrò ní àyè rẹ̀+Nígbà tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun bá bínú gidigidi ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná.
26 Nígbà yẹn, ohùn rẹ̀ mi ayé jìgìjìgì,+ àmọ́ ní báyìí, ó ti ṣèlérí pé: “Lẹ́ẹ̀kan sí i, kì í ṣe ayé nìkan ni màá mì jìgìjìgì, màá mi ọ̀run pẹ̀lú.”+