2 Sámúẹ́lì 22:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ò ń gba àwọn ẹni rírẹlẹ̀ là,+Ṣùgbọ́n o kì í fi ojú rere wo àwọn agbéraga, o sì ń rẹ̀ wọ́n wálẹ̀.+ Àìsáyà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ojú èèyàn tó ń gbéra ga máa wálẹ̀,A sì máa tẹrí ìgbéraga àwọn èèyàn ba.* Jèhófà nìkan la máa gbé ga ní ọjọ́ yẹn. Jémíìsì 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí Ó ń fi hàn tóbi ju èyí lọ. Ìdí nìyẹn tí ìwé mímọ́ fi sọ pé: “Ọlọ́run dojú ìjà kọ àwọn agbéraga,+ àmọ́ ó ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí àwọn onírẹ̀lẹ̀.”+
11 Ojú èèyàn tó ń gbéra ga máa wálẹ̀,A sì máa tẹrí ìgbéraga àwọn èèyàn ba.* Jèhófà nìkan la máa gbé ga ní ọjọ́ yẹn.
6 Àmọ́ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí Ó ń fi hàn tóbi ju èyí lọ. Ìdí nìyẹn tí ìwé mímọ́ fi sọ pé: “Ọlọ́run dojú ìjà kọ àwọn agbéraga,+ àmọ́ ó ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí àwọn onírẹ̀lẹ̀.”+