-
Sáàmù 142:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Fetí sí igbe mi fún ìrànlọ́wọ́,
Nítorí wọ́n ti bá mi kanlẹ̀.
Gbà mí lọ́wọ́ àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi,+
Torí wọ́n lágbára jù mí lọ.
-