Òwe 14:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹni tí kì í tètè bínú ní ìjìnlẹ̀ òye,+Àmọ́ ẹni tí kò ní sùúrù ń fi ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ hàn.+ Éfésù 4:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Tí inú bá bí yín, ẹ má ṣẹ̀;+ ẹ má ṣe jẹ́ kí oòrùn wọ̀ bá yín nínú ìbínú;+