Sáàmù 34:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìṣòro* olódodo máa ń pọ̀,+Àmọ́ Jèhófà ń gbà á sílẹ̀ nínú gbogbo rẹ̀.+ Òwe 24:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí olódodo lè ṣubú ní ìgbà méje, á sì tún dìde,+Àmọ́ àjálù yóò mú kí ẹni burúkú ṣubú pátápátá.+
16 Nítorí olódodo lè ṣubú ní ìgbà méje, á sì tún dìde,+Àmọ́ àjálù yóò mú kí ẹni burúkú ṣubú pátápátá.+