Sáàmù 77:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní ọjọ́ wàhálà mi, mo wá Jèhófà.+ Ní òru, mi ò dẹ́kun* títẹ́wọ́ àdúrà sí i. Síbẹ̀, mi* ò gba ìtùnú.
2 Ní ọjọ́ wàhálà mi, mo wá Jèhófà.+ Ní òru, mi ò dẹ́kun* títẹ́wọ́ àdúrà sí i. Síbẹ̀, mi* ò gba ìtùnú.