Òwe 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ahọ́n ní agbára láti fa ikú tàbí ìyè;+Àwọn tó bá fẹ́ràn láti máa lò ó yóò jẹ èrè rẹ̀.+