2 Kíróníkà 20:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n jẹ́ àtọmọdọ́mọ àwọn ọmọ Kóhátì+ àti àwọn ọmọ Kórà dìde láti fi ohùn tó ròkè yin Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+
19 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n jẹ́ àtọmọdọ́mọ àwọn ọmọ Kóhátì+ àti àwọn ọmọ Kórà dìde láti fi ohùn tó ròkè yin Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+