Ẹ́kísódù 14:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà ìṣọ́ òwúrọ̀,* Jèhófà wo àwùjọ àwọn ará Íjíbítì látinú ọwọ̀n iná* àti ìkùukùu,+ ó sì mú kí àwùjọ àwọn ará Íjíbítì dà rú.
24 Nígbà ìṣọ́ òwúrọ̀,* Jèhófà wo àwùjọ àwọn ará Íjíbítì látinú ọwọ̀n iná* àti ìkùukùu,+ ó sì mú kí àwùjọ àwọn ará Íjíbítì dà rú.