-
Jẹ́nẹ́sísì 9:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ọlọ́run súre fún Nóà àti àwọn ọmọ rẹ̀, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ máa bímọ, kí ẹ pọ̀, kí ẹ sì kún ayé.+ 2 Gbogbo ohun alààyè tó wà láyé, gbogbo ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, gbogbo ohun tó ń rìn lórí ilẹ̀ àti gbogbo ẹja inú òkun yóò máa bẹ̀rù yín, wọ́n á sì máa wárìrì torí yín. Wọ́n ti wà ní ìkáwọ́ yín báyìí.*+
-