2 Sámúẹ́lì 11:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Dáfídì rán ẹnì kan láti lọ wádìí nípa obìnrin náà, ẹni náà sì wá jábọ̀ pé: “Ṣebí Bátí-ṣébà+ ọmọ Élíámù+ ìyàwó Ùráyà+ ọmọ Hétì ni.”+
3 Dáfídì rán ẹnì kan láti lọ wádìí nípa obìnrin náà, ẹni náà sì wá jábọ̀ pé: “Ṣebí Bátí-ṣébà+ ọmọ Élíámù+ ìyàwó Ùráyà+ ọmọ Hétì ni.”+