-
Diutarónómì 32:45-47Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
45 Lẹ́yìn tí Mósè bá gbogbo Ísírẹ́lì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí tán, 46 ó sọ fún wọn pé: “Ẹ fi gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo fi kìlọ̀ fún yín lónìí+ sọ́kàn, kí ẹ lè pàṣẹ fún àwọn ọmọ yín pé, kí wọ́n rí i pé àwọn ń tẹ̀ lé gbogbo ọ̀rọ̀ Òfin+ yìí. 47 Torí èyí kì í ṣe ọ̀rọ̀ tí kò wúlò fún yín, àmọ́ òun ló máa mú kí ẹ wà láàyè,+ ọ̀rọ̀ yìí sì máa mú kí ẹ̀mí yín gùn lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń sọdá Jọ́dánì lọ gbà.”
-