Òwe 31:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Má fi okun rẹ fún àwọn obìnrin,+Má sì tọ ọ̀nà tó ń fa ìparun bá àwọn ọba.+ Lúùkù 15:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Àmọ́ gbàrà tí ọmọ rẹ yìí dé, ẹni tó lo àwọn ohun ìní rẹ nílòkulò* pẹ̀lú àwọn aṣẹ́wó, o dúńbú ọmọ màlúù tó sanra fún un.’
30 Àmọ́ gbàrà tí ọmọ rẹ yìí dé, ẹni tó lo àwọn ohun ìní rẹ nílòkulò* pẹ̀lú àwọn aṣẹ́wó, o dúńbú ọmọ màlúù tó sanra fún un.’