Òwe 16:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Èèyàn tí kò ní láárí máa ń hú ohun tí kò dáa jáde;+Ọ̀rọ̀ rẹ̀ dà bí iná tó ń jóni.+ Jémíìsì 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Bákan náà, ahọ́n jẹ́ iná.+ Ahọ́n dúró fún ayé àìṣòdodo lára àwọn ẹ̀yà ara wa, torí ó máa ń sọ gbogbo ara di aláìmọ́,+ ó sì máa ń dáná sí gbogbo ìgbésí ayé* ẹ̀dá, iná Gẹ̀hẹ́nà* á sì sun òun náà.
6 Bákan náà, ahọ́n jẹ́ iná.+ Ahọ́n dúró fún ayé àìṣòdodo lára àwọn ẹ̀yà ara wa, torí ó máa ń sọ gbogbo ara di aláìmọ́,+ ó sì máa ń dáná sí gbogbo ìgbésí ayé* ẹ̀dá, iná Gẹ̀hẹ́nà* á sì sun òun náà.