Òwe 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí ètè obìnrin oníwàkiwà* ń kán tótó bí afárá oyin,+Ọ̀rọ̀* rẹ̀ sì tuni lára ju òróró lọ.+ Òwe 7:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Sọ fún ọgbọ́n pé, “Arábìnrin mi ni ọ́,”Kí o sì pe òye ní “ìbátan mi,” 5 Láti dáàbò bò ọ́ lọ́wọ́ obìnrin oníwàkiwà,*+Lọ́wọ́ obìnrin oníṣekúṣe* àti àwọn ọ̀rọ̀ dídùn* rẹ̀.+
4 Sọ fún ọgbọ́n pé, “Arábìnrin mi ni ọ́,”Kí o sì pe òye ní “ìbátan mi,” 5 Láti dáàbò bò ọ́ lọ́wọ́ obìnrin oníwàkiwà,*+Lọ́wọ́ obìnrin oníṣekúṣe* àti àwọn ọ̀rọ̀ dídùn* rẹ̀.+