Òwe 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọlọ́gbọ́n máa ń fetí sílẹ̀, á sì kọ́ ẹ̀kọ́ sí i;+Olóye máa ń gba ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n+ Òwe 15:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ẹni tó ń fetí sí ìbáwí tó ń fúnni ní ìyè,Àárín àwọn ọlọ́gbọ́n ló ń gbé.+ Òwe 17:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìbáwí tí a fún olóye máa ń ṣe é láǹfààní púpọ̀+Ju lílu òmùgọ̀ ní ọgọ́rùn-ún ìgbà.+ Òwe 25:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bíi yẹtí wúrà àti ohun ọ̀ṣọ́ tí wọ́n fi wúrà tó dára ṣeNi ọlọ́gbọ́n tó ń báni wí jẹ́ ní etí ẹni tó ń gbọ́ràn.+
5 Ọlọ́gbọ́n máa ń fetí sílẹ̀, á sì kọ́ ẹ̀kọ́ sí i;+Olóye máa ń gba ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n+ Òwe 15:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ẹni tó ń fetí sí ìbáwí tó ń fúnni ní ìyè,Àárín àwọn ọlọ́gbọ́n ló ń gbé.+ Òwe 17:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìbáwí tí a fún olóye máa ń ṣe é láǹfààní púpọ̀+Ju lílu òmùgọ̀ ní ọgọ́rùn-ún ìgbà.+ Òwe 25:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bíi yẹtí wúrà àti ohun ọ̀ṣọ́ tí wọ́n fi wúrà tó dára ṣeNi ọlọ́gbọ́n tó ń báni wí jẹ́ ní etí ẹni tó ń gbọ́ràn.+
12 Bíi yẹtí wúrà àti ohun ọ̀ṣọ́ tí wọ́n fi wúrà tó dára ṣeNi ọlọ́gbọ́n tó ń báni wí jẹ́ ní etí ẹni tó ń gbọ́ràn.+