Sáàmù 51:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wò ó! Inú rẹ máa ń dùn sí òtítọ́ tó ti ọ̀kan ẹni wá;+Kọ́ inú mi lọ́hùn-ún* ní ọgbọ́n tòótọ́. Òwe 15:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹbọ ẹni burúkú jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+Àmọ́ àdúrà àwọn adúróṣinṣin máa ń múnú Rẹ̀ dùn.+