5 Ṣùgbọ́n, àwọn kan tó wá látinú ẹ̀ya ìsìn àwọn Farisí, àmọ́ tí wọ́n ti di onígbàgbọ́ dìde lórí ìjókòó wọn, wọ́n sì sọ pé: “Ó pọn dandan kí a dádọ̀dọ́ wọn, kí a sì pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n máa pa Òfin Mósè mọ́.”+
6 Torí náà, àwọn àpọ́sítélì àti àwọn alàgbà kóra jọ láti gbé ọ̀rọ̀ yìí yẹ̀ wò.