-
2 Sámúẹ́lì 4:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Àmọ́, Dáfídì dá Rékábù àti Báánà arákùnrin rẹ̀, àwọn ọmọ Rímónì ará Béérótì lóhùn pé: “Bí Jèhófà ẹni tí ó yọ mí* nínú gbogbo wàhálà+ ti wà láàyè, 10 nígbà tí ẹnì kan wá sọ fún mi pé, ‘Wò ó, Sọ́ọ̀lù ti kú,’+ ó rò pé ìròyìn ayọ̀ lòun mú wá fún mi, mo gbá a mú, mo sì pa á+ ní Síkílágì. Nǹkan tí mo fi san èrè iṣẹ́ tó wá jẹ́ nìyẹn!
-