-
Jémíìsì 5:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Wúrà àti fàdákà yín ti dípẹtà, ìpẹtà wọn máa jẹ́ ẹ̀rí lòdì sí yín, ó sì máa jẹ ẹran ara yín. Ohun tí ẹ kó jọ máa dà bí iná ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn.+ 4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+
-