9 Torí pé ọlọ̀tẹ̀ èèyàn ni wọ́n,+ àwọn ẹlẹ́tàn ọmọ,+
Àwọn ọmọ tí kò fẹ́ gbọ́ òfin Jèhófà.+
10 Wọ́n ń sọ fún àwọn aríran pé, ‘Ẹ má ṣe ríran,’
Àti fún àwọn olùríran pé, ‘Ẹ má sọ àwọn ìran tó jẹ́ òótọ́ fún wa.+
Ọ̀rọ̀ dídùn ni kí ẹ bá wa sọ; ìran ẹ̀tàn ni kí ẹ máa rí.+