Òwe 18:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọkàn gíga ló ń ṣáájú ìṣubú,+Ìrẹ̀lẹ̀ ló sì ń ṣáájú ògo.+ Jémíìsì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ rẹ ara yín sílẹ̀ ní ojú Jèhófà,*+ ó sì máa gbé yín ga.+