11 Tí wọ́n bá mú yín wọlé síwájú ibi táwọn èèyàn pé jọ sí, síwájú àwọn aṣojú ìjọba àti àwọn aláṣẹ, ẹ má ṣàníyàn nípa bí ẹ ṣe máa sọ̀rọ̀ tàbí ọ̀rọ̀ tí ẹ máa fi gbèjà ara yín tàbí ohun tí ẹ máa sọ,+ 12 torí ní wákàtí yẹn gan-an, ẹ̀mí mímọ́ máa kọ́ yín ní àwọn ohun tó yẹ kí ẹ sọ.”+