-
Òwe 22:26, 27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Má ṣe wà lára àwọn tó ń bọ ọwọ́ nínú ẹ̀jẹ́,
Tí wọ́n ń ṣe onídùúró fún ẹni tó ń yá owó.+
27 Tí o kò bá rí i san,
Wọ́n á gba ibùsùn rẹ kúrò lábẹ́ rẹ!
-