Róòmù 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí mo jẹ́rìí wọn pé wọ́n ní ìtara fún Ọlọ́run,+ àmọ́ kì í ṣe pẹ̀lú ìmọ̀ tó péye.