-
Òwe 24:33, 34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Oorun díẹ̀, ìtòògbé díẹ̀,
Kíkáwọ́ gbera díẹ̀ láti sinmi,
34 Ipò òṣì rẹ yóò sì dé bí olè,
Àti àìní rẹ bí ọkùnrin tó dìhámọ́ra.+
-
-
2 Tẹsalóníkà 3:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Kódà, nígbà tí a wà lọ́dọ̀ yín, a máa ń pa àṣẹ yìí fún yín pé: “Tí ẹnikẹ́ni ò bá fẹ́ ṣiṣẹ́, kó má jẹun.”+
-