13 Lẹ́yìn ọjọ́ mélòó kan, èyí àbúrò kó gbogbo ohun tó jẹ́ tirẹ̀ jọ, ó sì rìnrìn àjò lọ sí ilẹ̀ tó jìnnà gan-an, ibẹ̀ ló ti ń gbé ìgbésí ayé oníwà pálapàla, tó sì lo àwọn ohun ìní rẹ̀ nílòkulò. 14 Nígbà tó ti ná gbogbo rẹ̀ tán, ìyàn mú gan-an ní gbogbo ilẹ̀ yẹn, ó sì di aláìní.