Jóòbù 31:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ṣé inú mi ti dùn rí torí pé ọ̀tá mi pa run,+Tàbí kí n fi ṣe yẹ̀yẹ́ torí ohun burúkú ṣẹlẹ̀ sí i? Òwe 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹni tó bá ń fi aláìní ṣẹ̀sín ń gan Ẹni tó dá a,+Ẹni tó bá sì ń yọ̀ nítorí àjálù tó bá ẹlòmíì kò ní lọ láìjìyà.+ Òwe 25:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Tí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ,* fún un ní oúnjẹ jẹ;Tí òùngbẹ bá sì ń gbẹ ẹ́, fún un ní omi mu,+22 Torí ṣe ni wàá máa kó ẹyin iná jọ lé e lórí,*+Jèhófà yóò sì san èrè fún ọ.
5 Ẹni tó bá ń fi aláìní ṣẹ̀sín ń gan Ẹni tó dá a,+Ẹni tó bá sì ń yọ̀ nítorí àjálù tó bá ẹlòmíì kò ní lọ láìjìyà.+
21 Tí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ,* fún un ní oúnjẹ jẹ;Tí òùngbẹ bá sì ń gbẹ ẹ́, fún un ní omi mu,+22 Torí ṣe ni wàá máa kó ẹyin iná jọ lé e lórí,*+Jèhófà yóò sì san èrè fún ọ.