-
Jẹ́nẹ́sísì 32:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 ó pàṣẹ fún wọn pé: “Ohun tí ẹ máa sọ fún Ísọ̀ olúwa mi nìyí, ‘Ohun tí Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ sọ nìyí: “Ó ti pẹ́ tí mo ti ń gbé* lọ́dọ̀ Lábánì títí di báyìí.+ 5 Mo ti ní àwọn akọ màlúù, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àgùntàn, àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin,+ mo sì ń ránṣẹ́ yìí sí olúwa mi láti fi èyí tó o létí, kí n lè rí ojúure rẹ.”’”
-