1 Sámúẹ́lì 20:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ni Sọ́ọ̀lù bá ju ọ̀kọ̀ sí i láti fi gún un,+ Jónátánì sì wá mọ̀ pé bàbá òun ti pinnu láti pa Dáfídì.+ Òwe 16:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹni tí kì í tètè bínú+ sàn ju akíkanjú ọkùnrin,Ẹni tó sì ń kápá ìbínú rẹ̀* sàn ju ẹni tó ṣẹ́gun ìlú.+ Òwe 22:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Má ṣe bá onínúfùfù kẹ́gbẹ́,Má sì bá ẹni tó máa ń tètè bínú da nǹkan pọ̀,25 Kí o má bàa kọ́ àwọn ọ̀nà rẹ̀,Kí o sì kó ara* rẹ sínú ìdẹkùn.+ Òwe 29:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Gbogbo bí ọ̀rọ̀ ṣe rí lára* òmùgọ̀ ló máa ń sọ jáde,+Àmọ́ ọlọ́gbọ́n máa ń mú sùúrù.+
33 Ni Sọ́ọ̀lù bá ju ọ̀kọ̀ sí i láti fi gún un,+ Jónátánì sì wá mọ̀ pé bàbá òun ti pinnu láti pa Dáfídì.+
32 Ẹni tí kì í tètè bínú+ sàn ju akíkanjú ọkùnrin,Ẹni tó sì ń kápá ìbínú rẹ̀* sàn ju ẹni tó ṣẹ́gun ìlú.+
24 Má ṣe bá onínúfùfù kẹ́gbẹ́,Má sì bá ẹni tó máa ń tètè bínú da nǹkan pọ̀,25 Kí o má bàa kọ́ àwọn ọ̀nà rẹ̀,Kí o sì kó ara* rẹ sínú ìdẹkùn.+