Òwe 3:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Má ṣe bá ẹnì kankan jà láìnídìí+Nígbà tí kò ṣe aburú kankan sí ọ.+ Òwe 16:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Oníwàhálà* máa ń dá ìyapa sílẹ̀,+Abanijẹ́ sì máa ń tú àwọn ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ká.+ Òwe 17:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ìbẹ̀rẹ̀ ìjà dà bí ìgbà téèyàn ṣí ibú omi sílẹ̀;*Kí ìjà tó bẹ́, fi ibẹ̀ sílẹ̀.+