1 Sámúẹ́lì 25:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Kí olúwa mi jọ̀wọ́ má fiyè sí Nábálì ọkùnrin aláìníláárí+ yìí, nítorí bí orúkọ rẹ̀ ti jẹ́, ni òun náà jẹ́. Nábálì* ni orúkọ rẹ̀, ìwà òmùgọ̀ ló sì ń hù. Àmọ́ èmi ìránṣẹ́bìnrin rẹ kò rí àwọn ọ̀dọ́kùnrin tí olúwa mi rán.
25 Kí olúwa mi jọ̀wọ́ má fiyè sí Nábálì ọkùnrin aláìníláárí+ yìí, nítorí bí orúkọ rẹ̀ ti jẹ́, ni òun náà jẹ́. Nábálì* ni orúkọ rẹ̀, ìwà òmùgọ̀ ló sì ń hù. Àmọ́ èmi ìránṣẹ́bìnrin rẹ kò rí àwọn ọ̀dọ́kùnrin tí olúwa mi rán.