Òwe 16:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó sàn kéèyàn ní díẹ̀ àmọ́ kó jẹ́ olóòótọ́+Ju kéèyàn fi èrú kó èrè púpọ̀ jọ.+ Òwe 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sàn kéèyàn jẹ́ aláìní àmọ́ kó máa rìn nínú ìwà títọ́+Ju kéèyàn jẹ́ òmùgọ̀ kó sì máa parọ́.+