Ẹ́sítà 8:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní gbogbo ìpínlẹ̀* àti gbogbo ìlú tí àṣẹ ọba àti òfin rẹ̀ dé, àwọn Júù ń yọ̀, inú wọn ń dùn, wọ́n ń se àsè, wọ́n sì ń ṣe àjọyọ̀. Ọ̀pọ̀ lára àwọn èèyàn ilẹ̀ náà bẹ̀rẹ̀ sí í pe ara wọn ní Júù,+ torí ẹ̀rù àwọn Júù ń bà wọ́n.
17 Ní gbogbo ìpínlẹ̀* àti gbogbo ìlú tí àṣẹ ọba àti òfin rẹ̀ dé, àwọn Júù ń yọ̀, inú wọn ń dùn, wọ́n ń se àsè, wọ́n sì ń ṣe àjọyọ̀. Ọ̀pọ̀ lára àwọn èèyàn ilẹ̀ náà bẹ̀rẹ̀ sí í pe ara wọn ní Júù,+ torí ẹ̀rù àwọn Júù ń bà wọ́n.