Oníwàásù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Má ṣe yánu sọ̀rọ̀ tàbí kí ọkàn rẹ sọ̀rọ̀ láìronú níwájú Ọlọ́run tòótọ́,+ nítorí Ọlọ́run tòótọ́ wà ní ọ̀run àmọ́ ìwọ wà ní ayé. Ìdí nìyẹn tó fi yẹ kí ọ̀rọ̀ rẹ mọ níwọ̀n.+ Jémíìsì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ mọ èyí: Ó yẹ kí gbogbo èèyàn yára láti gbọ́rọ̀, kí wọ́n lọ́ra láti sọ̀rọ̀,+ kí wọ́n má sì tètè máa bínú,+
2 Má ṣe yánu sọ̀rọ̀ tàbí kí ọkàn rẹ sọ̀rọ̀ láìronú níwájú Ọlọ́run tòótọ́,+ nítorí Ọlọ́run tòótọ́ wà ní ọ̀run àmọ́ ìwọ wà ní ayé. Ìdí nìyẹn tó fi yẹ kí ọ̀rọ̀ rẹ mọ níwọ̀n.+
19 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ mọ èyí: Ó yẹ kí gbogbo èèyàn yára láti gbọ́rọ̀, kí wọ́n lọ́ra láti sọ̀rọ̀,+ kí wọ́n má sì tètè máa bínú,+