Mátíù 10:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ẹ má bẹ̀rù àwọn tó ń pa ara àmọ́ tí wọn ò lè pa ọkàn;*+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ bẹ̀rù ẹni tó lè pa ọkàn àti ara run nínú Gẹ̀hẹ́nà.*+ Mátíù 26:75 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 75 Pétérù wá rántí ohun tí Jésù sọ, pé: “Kí àkùkọ tó kọ, o máa sẹ́ mi lẹ́ẹ̀mẹta.”+ Ló bá bọ́ síta, ó sì sunkún gidigidi.
28 Ẹ má bẹ̀rù àwọn tó ń pa ara àmọ́ tí wọn ò lè pa ọkàn;*+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ bẹ̀rù ẹni tó lè pa ọkàn àti ara run nínú Gẹ̀hẹ́nà.*+
75 Pétérù wá rántí ohun tí Jésù sọ, pé: “Kí àkùkọ tó kọ, o máa sẹ́ mi lẹ́ẹ̀mẹta.”+ Ló bá bọ́ síta, ó sì sunkún gidigidi.