Dáníẹ́lì 6:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọba wá pàṣẹ, wọ́n mú àwọn ọkùnrin tó fẹ̀sùn* kan Dáníẹ́lì wá, wọ́n sì jù wọ́n sínú ihò kìnnìún, pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn àtàwọn ìyàwó wọn. Àmọ́, wọn ò tíì dé ìsàlẹ̀ ihò náà tí àwọn kìnnìún náà fi bò wọ́n, wọ́n sì fọ́ gbogbo egungun wọn túútúú.+
24 Ọba wá pàṣẹ, wọ́n mú àwọn ọkùnrin tó fẹ̀sùn* kan Dáníẹ́lì wá, wọ́n sì jù wọ́n sínú ihò kìnnìún, pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn àtàwọn ìyàwó wọn. Àmọ́, wọn ò tíì dé ìsàlẹ̀ ihò náà tí àwọn kìnnìún náà fi bò wọ́n, wọ́n sì fọ́ gbogbo egungun wọn túútúú.+