Òwe 7:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ni mo bá rí obìnrin kan tó wá pàdé rẹ̀,Ó múra bí* aṣẹ́wó,+ ó ní ọkàn àrékérekè. 11 Ó jẹ́ aláriwo àti aláfojúdi.+ Kì í* dúró sílé.
10 Ni mo bá rí obìnrin kan tó wá pàdé rẹ̀,Ó múra bí* aṣẹ́wó,+ ó ní ọkàn àrékérekè. 11 Ó jẹ́ aláriwo àti aláfojúdi.+ Kì í* dúró sílé.