Léfítíkù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “‘Tàbí tí ẹnì* kan bá búra láìronú jinlẹ̀ pé òun máa ṣe ohun kan, yálà ohun tó dáa tàbí ohun tí kò dáa, ohun yòówù kó jẹ́, tí kò sì mọ̀, àmọ́ tó wá mọ̀ pé òun ti búra láìronú jinlẹ̀, ó ti jẹ̀bi.*+
4 “‘Tàbí tí ẹnì* kan bá búra láìronú jinlẹ̀ pé òun máa ṣe ohun kan, yálà ohun tó dáa tàbí ohun tí kò dáa, ohun yòówù kó jẹ́, tí kò sì mọ̀, àmọ́ tó wá mọ̀ pé òun ti búra láìronú jinlẹ̀, ó ti jẹ̀bi.*+