Òwe 23:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Má fi wàhálà pa ara rẹ torí kí o lè kó ọrọ̀ jọ.+ Fara balẹ̀ kí o sì lo òye.* 5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+ Mátíù 6:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Ẹ má to ìṣúra pa mọ́ fún ara yín ní ayé mọ́,+ níbi tí òólá* ti ń jẹ nǹkan run, tí nǹkan ti ń dípẹtà, tí àwọn olè ń fọ́lé, tí wọ́n sì ń jalè.
4 Má fi wàhálà pa ara rẹ torí kí o lè kó ọrọ̀ jọ.+ Fara balẹ̀ kí o sì lo òye.* 5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+
19 “Ẹ má to ìṣúra pa mọ́ fún ara yín ní ayé mọ́,+ níbi tí òólá* ti ń jẹ nǹkan run, tí nǹkan ti ń dípẹtà, tí àwọn olè ń fọ́lé, tí wọ́n sì ń jalè.