Sáàmù 104:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àti wáìnì tó ń mú ọkàn èèyàn yọ̀,+Òróró tó ń mú kí ojú dánÀti oúnjẹ tó ń gbé ẹ̀mí ẹni kíkú ró.+ Oníwàásù 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Máa lọ, máa fi ayọ̀ jẹ oúnjẹ rẹ, kí o sì máa fi ìdùnnú mu wáìnì rẹ,+ nítorí inú Ọlọ́run tòótọ́ ti dùn sí àwọn iṣẹ́ rẹ.+
7 Máa lọ, máa fi ayọ̀ jẹ oúnjẹ rẹ, kí o sì máa fi ìdùnnú mu wáìnì rẹ,+ nítorí inú Ọlọ́run tòótọ́ ti dùn sí àwọn iṣẹ́ rẹ.+