Oníwàásù 6:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nítorí àǹfààní wo ni ọlọ́gbọ́n ní lórí òmùgọ̀?+ Tàbí àǹfààní kí ló jẹ́ fún aláìní pé ó mọ bí èèyàn ṣe ń tọ́jú ara rẹ̀?* Róòmù 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé, bí ẹ̀ṣẹ̀ ṣe tipasẹ̀ ẹnì kan wọ ayé, tí ikú sì wá nípasẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni ikú ṣe tàn dé ọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn torí pé gbogbo wọn ti dẹ́ṣẹ̀+—.
8 Nítorí àǹfààní wo ni ọlọ́gbọ́n ní lórí òmùgọ̀?+ Tàbí àǹfààní kí ló jẹ́ fún aláìní pé ó mọ bí èèyàn ṣe ń tọ́jú ara rẹ̀?*
12 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé, bí ẹ̀ṣẹ̀ ṣe tipasẹ̀ ẹnì kan wọ ayé, tí ikú sì wá nípasẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni ikú ṣe tàn dé ọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn torí pé gbogbo wọn ti dẹ́ṣẹ̀+—.