Jẹ́nẹ́sísì 41:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Fáráò bá ránṣẹ́ pe Jósẹ́fù,+ wọ́n sì sáré mú un wá látinú ẹ̀wọ̀n.*+ Ó fá irun rẹ̀, ó pààrọ̀ aṣọ rẹ̀, ó sì wọlé lọ bá Fáráò. Jẹ́nẹ́sísì 41:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Ìwọ ni màá fi ṣe olórí ilé mi, gbogbo àwọn èèyàn mi yóò sì máa ṣègbọràn sí ọ délẹ̀délẹ̀.+ Ipò ọba* mi nìkan ni màá fi jù ọ́ lọ.”
14 Fáráò bá ránṣẹ́ pe Jósẹ́fù,+ wọ́n sì sáré mú un wá látinú ẹ̀wọ̀n.*+ Ó fá irun rẹ̀, ó pààrọ̀ aṣọ rẹ̀, ó sì wọlé lọ bá Fáráò.
40 Ìwọ ni màá fi ṣe olórí ilé mi, gbogbo àwọn èèyàn mi yóò sì máa ṣègbọràn sí ọ délẹ̀délẹ̀.+ Ipò ọba* mi nìkan ni màá fi jù ọ́ lọ.”