2 Kíróníkà 20:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìwọ Ọlọ́run wa, ṣebí ìwọ lo lé àwọn tó ń gbé ilẹ̀ yìí kúrò níwájú àwọn èèyàn rẹ Ísírẹ́lì, tí o sì wá fún àtọmọdọ́mọ* ọ̀rẹ́ rẹ Ábúráhámù pé kí ó jẹ́ ohun ìní wọn títí lọ?+ Jémíìsì 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 a sì mú ìwé mímọ́ náà ṣẹ tó sọ pé: “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* a sì kà á sí òdodo fún un,”+ a sì wá ń pè é ní ọ̀rẹ́ Jèhófà.*+
7 Ìwọ Ọlọ́run wa, ṣebí ìwọ lo lé àwọn tó ń gbé ilẹ̀ yìí kúrò níwájú àwọn èèyàn rẹ Ísírẹ́lì, tí o sì wá fún àtọmọdọ́mọ* ọ̀rẹ́ rẹ Ábúráhámù pé kí ó jẹ́ ohun ìní wọn títí lọ?+
23 a sì mú ìwé mímọ́ náà ṣẹ tó sọ pé: “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* a sì kà á sí òdodo fún un,”+ a sì wá ń pè é ní ọ̀rẹ́ Jèhófà.*+