Jóẹ́lì 3:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wáìnì dídùn yóò máa sẹ̀ láti orí àwọn òkè ní ọjọ́ yẹn,+Wàrà yóò máa ṣàn lórí àwọn òkè kéékèèké,Gbogbo omi odò Júdà yóò sì máa ṣàn. Omi yóò sun láti ilé Jèhófà,+Yóò sì bomi rin Àfonífojì Àwọn Igi Bọn-ọ̀n-ní.
18 Wáìnì dídùn yóò máa sẹ̀ láti orí àwọn òkè ní ọjọ́ yẹn,+Wàrà yóò máa ṣàn lórí àwọn òkè kéékèèké,Gbogbo omi odò Júdà yóò sì máa ṣàn. Omi yóò sun láti ilé Jèhófà,+Yóò sì bomi rin Àfonífojì Àwọn Igi Bọn-ọ̀n-ní.