-
1 Tímótì 2:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Èyí dáa, ó sì ní ìtẹ́wọ́gbà lójú Ọlọ́run, Olùgbàlà wa,+
-
-
Júùdù 25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ọlọ́run kan ṣoṣo tó jẹ́ Olùgbàlà wa nípasẹ̀ Jésù Kristi Olúwa wa, ni kí ògo, ọlá, agbára àti àṣẹ máa jẹ́ tirẹ̀ láti ayérayé àti nísinsìnyí àti títí láé. Àmín.
-