Ẹ́kísódù 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Torí náà, sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: ‘Èmi ni Jèhófà, màá mú yín kúrò lábẹ́ àjàgà àwọn ará Íjíbítì, màá sì gbà yín sílẹ̀ lóko ẹrú.+ Màá fi apá mi tí mo nà jáde* àti àwọn ìdájọ́ tó rinlẹ̀ gbà yín pa dà.+ Jeremáyà 50:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Àmọ́, Olùtúnrà wọn lágbára.+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.+ Ó dájú pé á gba ẹjọ́ wọn rò,+Kí ó lè fún ilẹ̀ náà ní ìsinmi+Kí ó sì mú rúkèrúdò bá àwọn tó ń gbé ní Bábílónì.”+
6 “Torí náà, sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: ‘Èmi ni Jèhófà, màá mú yín kúrò lábẹ́ àjàgà àwọn ará Íjíbítì, màá sì gbà yín sílẹ̀ lóko ẹrú.+ Màá fi apá mi tí mo nà jáde* àti àwọn ìdájọ́ tó rinlẹ̀ gbà yín pa dà.+
34 Àmọ́, Olùtúnrà wọn lágbára.+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.+ Ó dájú pé á gba ẹjọ́ wọn rò,+Kí ó lè fún ilẹ̀ náà ní ìsinmi+Kí ó sì mú rúkèrúdò bá àwọn tó ń gbé ní Bábílónì.”+