Àìsáyà 40:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Oníṣẹ́ ọnà ṣe ère,*Oníṣẹ́ irin fi wúrà bò ó,+Ó sì fi fàdákà rọ ẹ̀wọ̀n. Àìsáyà 41:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí náà, oníṣẹ́ ọnà ń fún oníṣẹ́ irin+ lókun;Ẹni tó ń fi òòlù irin* lu nǹkan di pẹlẹbẹŃ fún ẹni tó ń fi òòlù lu nǹkan lórí irin lókun. Ó ń sọ nípa ohun tí wọ́n jó pọ̀ pé: “Ó dáa.” Wọ́n wá fi ìṣó kàn án, kó má bàa ṣubú. Àìsáyà 46:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn kan wà tó ń kó wúrà jáde yàlàyòlò látinú àpò wọn;Wọ́n ń wọn fàdákà lórí òṣùwọ̀n. Wọ́n gba oníṣẹ́ irin síṣẹ́, ó sì fi ṣe ọlọ́run.+ Wọ́n wá wólẹ̀, àní, wọ́n jọ́sìn rẹ̀.*+
7 Torí náà, oníṣẹ́ ọnà ń fún oníṣẹ́ irin+ lókun;Ẹni tó ń fi òòlù irin* lu nǹkan di pẹlẹbẹŃ fún ẹni tó ń fi òòlù lu nǹkan lórí irin lókun. Ó ń sọ nípa ohun tí wọ́n jó pọ̀ pé: “Ó dáa.” Wọ́n wá fi ìṣó kàn án, kó má bàa ṣubú.
6 Àwọn kan wà tó ń kó wúrà jáde yàlàyòlò látinú àpò wọn;Wọ́n ń wọn fàdákà lórí òṣùwọ̀n. Wọ́n gba oníṣẹ́ irin síṣẹ́, ó sì fi ṣe ọlọ́run.+ Wọ́n wá wólẹ̀, àní, wọ́n jọ́sìn rẹ̀.*+