-
Émọ́sì 3:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Tí èèyàn bá fun ìwo nínú ìlú, ǹjẹ́ àyà àwọn ará ìlú kò ní já?
Tí àjálù bá ṣẹlẹ̀ nínú ìlú, ǹjẹ́ kì í ṣe Jèhófà ló fà á?